Ìjọba àpapọ̀ ti bu ọwọ́ lu owó tó lé ní bilionu metadinlogbon naira fún isẹ́ ọ̀pópónà àti afárá Bodo-Bonny ní ìlú Rivers àti pópónà Idah-Nsukka.
Minisita fun iṣe ati igbele, Arakunrin Babatunde Fashọla lo fi idi eyi mulẹ nigba ti o n jiroro pẹlu awọn oniroyin lọjọ isẹgun
Tolulọpẹ Akinṣẹyẹ
Leave a Reply