Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ jẹ́ kí àtúnse bá ẹ̀ka ètò ìdájọ́- Osinbajo

0 122

Igbakeji aarẹ orilẹ ede Naijria, ọjọgbọn Yemi Osinbajo  ti rọ awọn to di òpó eto idajọ mu lorilẹ ede Naijiria, lati se atunse to mọnyan lori ba ẹka eto idajọ lorilẹ ede yii , ki awọn eniyan lee ni igbagbọ ninu wọn.

Nigba ti o tẹsiwaju ninu ọrọ rẹ, nibi apero idanilẹkọọ ti Wole Olanipekun m ni eyi ti o jẹ ẹlẹẹkeji rẹ, ti yoo waye , ọjọgbọn Yemi Osinbajo ni, ti ẹ ba foju wo eto idajọ , awọn adajọ, agbajọro ati awọn kootu to wa  lorilẹ ede Naijiria yii, nilo atunse to mọnyan lori, ki wọn lee duro sinsin ninu eto idajọ wọn fun aadọta ọdun  (50 years) to n bọ.

Apero idanilẹkọọ ọhun waye lati fi se ayẹyẹ ogbontarigi adajọ ati agbẹjọro , oloye Wole Olanipekun, ti o pe ọmọ ọdun aadọrin ( 70 years)

Leave A Reply

Your email address will not be published.