Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Bu Ọwọ́ Lu Owó Tó Lé Ní Bilionu Metadinlogbọn Fún isẹ́ ọ̀pópónà

0 109

Ìjọba àpapọ̀ ti bu ọwọ́ lu owó tó lé ní bilionu metadinlogbon naira fún isẹ́ ọ̀pópónà àti afárá Bodo-Bonny ní ìlú Rivers àti pópónà Idah-Nsukka.

Minisita fun iṣe ati igbele, Arakunrin Babatunde Fashọla lo fi idi eyi mulẹ nigba ti o n jiroro pẹlu awọn oniroyin lọjọ isẹgun

 

 

 

Tolulọpẹ Akinṣẹyẹ

Leave A Reply

Your email address will not be published.