Àwọn ènìyàn mẹ́rìndín-láàdọ́rùn ún míràn tún ti ní ààrùn covid
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Nàìjíríà tún ti rí àwọn ènìyàn mẹ́rìndín-láàdọ́rùn ún míràn tún ti kó ààrùn covid jákèjádò orílẹ̀-èdè.
Ile-iṣẹ to n mojuto ajakalẹ aarun ni o fi taye leti lori bo ṣe n lọ.Ile –iṣẹ naa sọ pe awọn eniyan wọnyii jẹyọ ni ipinlẹ meje.
Ipinlẹ Kaduna( mọkanle-logoji ), Lagos-( mẹrinle-logun ), Osun-( mẹwa) , Bauchi-(mẹfa ), Ekiti- meji ), Ondo-(meji), Edo-(ẹyọkan) gẹgẹ bii ile-iṣẹ naa ṣe ṣalaye.
Lọwọlọwọ bayii,eniyan ẹgbẹ́ẹ́ẹdógún- le- ni- ọ̀kẹ́- mẹ̀wá- abo- o- din- ni- ẹ̀ta- din- làádọ́rùn lo ti ko aarun naa, ẹgbàáta- le- ni- ọ̀kẹ́- mẹ̀wá- o- le- ni- ọ̀kan- din- ni- ọ́rin- lelọ́ọ̀dúnrún eniyan ti gba iwosan ti ẹ̀fà le ni ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ẹ́ẹdógún si ti jẹpe oluwa.
Leave a Reply