Oluranlọwọ aarẹ lori eto aabo lorile ede Naijria, Babagana Monguno ti gbosuba fu ikọ ọmọ ogun orile ede Naijria fun gudu gudu meje yaya mẹfa ti wọn se lati fẹyin olori ikọ̀ ọlọtẹ to n da ilẹ Afirika laamu iyẹn Abu Mussab Al-Barnawi balẹ̀
O sọrọ yii lọjọBọ nile aarẹ lẹyin ipade ti wọn se pẹlu aarẹ Buhari lori eto aabo lorilẹ ede Naijiria lasiko to n ba awọn akọroyin sọrọ.
Monguno tun sọ pe o yẹ ka gboriyn fun ile-isẹ́ ọmọ ogun orilẹ ede Naijiria fun gudu, gudu meje, yaya mẹfa ti wọn se,
Leave a Reply