Take a fresh look at your lifestyle.

Ikọ̀ ọmọ ogun Nàíjíríà fẹ̀yìn ọlọ̀tẹ̀ Abu Mussab Al-Barnawi balẹ̀

0 300

Oluranlọwọ aarẹ lori eto aabo lorile ede Naijria,  Babagana Monguno  ti gbosuba fu ikọ ọmọ ogun orile ede Naijria fun gudu gudu meje yaya mẹfa ti wọn se lati fẹyin  olori ikọ̀ ọlọtẹ  to n da ilẹ Afirika laamu iyẹn Abu Mussab Al-Barnawi  balẹ̀

O sọrọ yii lọjọBọ nile aarẹ lẹyin ipade ti wọn se pẹlu aarẹ Buhari lori eto aabo lorilẹ ede Naijiria  lasiko to n ba awọn akọroyin sọrọ.

Monguno tun sọ pe o yẹ ka gboriyn fun ile-isẹ́ ọmọ ogun orilẹ ede Naijiria fun gudu, gudu meje, yaya mẹfa ti wọn se,

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button