Ìgbìmọ̀ tó ńmójútó ètò ìṣèdánwò àpapọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà[NECO], ti sún ìdánwò gbogbogboò 2021,sí àwọn ilé-ẹ̀kọ́ àpapọ̀ sí ọjọ karùún,ọjọ́ àbámẹ́ta oṣù kẹfà,ọdún 2021.
Agbẹnusọ fun igbimọ naa, Abduazeez Sani, fidi ẹ mulẹ ninu atẹjade kan to fisita ni ọjọọru pe, koda ijọba apapọ ti fi ontẹ lu.
Iforukọsilẹ awọn oludije gẹgẹbi alaye naa, yoo tẹsiwaju titi di ọjọ tuntun fun idanwo naa.
Leave a Reply