Ààrẹ Muhammadu Buhari ti ní kí olùdarí ilé-isẹ́ ọkọ̀ oju omi,(Nigerian Ports Authority, NPA)Hadiza Bala Usman,lọ rọ ọ́ kún sílé ná, aarẹ Muhammadu Buhari tún wá fọwọ́sí ohun tí minisita tó ń mójútó ètò ìrìnnà lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà, Rotimi Amaechi,sọ láti yan ìgbìmọ̀ olùwádìí láti ṣe ìwádìí àwọn olùsàkoso ilé-isẹ́ ọ̀hún.
Bakan naa ni aarẹ Buhari wa yan oludari ẹka to n mojuto eto isiro ati isẹ́ , Mohammed Koko lati maa se oludari ile-isẹ́ naa.
Leave a Reply