Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19: Àwọn ènìyàn méjìdínlọ́gbọ̀n míràn tún ti jẹyọ

Ademọla Adepọju

155

Orílẹ̀ èdè Nàíjíríà tún ti ní àwọn ènìyàn méjìdínlọ́gbọ̀n(28) míràn tí wọ́n ti ní ààrùn Corona ìyẹn , COVID-19, báyìí , tí ó jẹ́ kí iye gbogbo àwọn tó ní ààrùn ọ̀hún jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbàta-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-le-ni-ọ̀kan-le-ni ọ́ọ̀dúnrún (165,301).

Ajọ to n mojuto ajakalẹ aarun lorilẹ ede Naijiria ,Nigeria Centre for Disease Control (NCDC) lo kede lori ẹrọ Twitter wọn.

Gẹgẹ bi ajọ naa se sọ pe , awọn eniyan mejidinlọgbọn naa ló wá lati awọn ipinlẹ mẹfa, ipinlẹ Eko, mẹwaa( 10), ipinlẹ Rivers meje(7) Kaduna , eyọ kan(1).

“Lagos-10 Rivers-7 Akwa Ibom-6 Delta-2 FCT-2 Kaduna-1.”

Ajọ naa tun kede pe, awọn eniyan ti iye wọn jẹ ẹ̀ẹ́dẹ́gbàta-le-ni-ọ̀kẹ́-mèje-abọ- le-ni-mẹ̀rin-le-ni-okòó-le-ni-irinwó (155,424) lo ti gba iwosan , nigba ti awọn eniyan ti iye wọn jẹ àrún-din-ni-ojì-din-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ọ̀kànlá( 2,065 ) si ti jẹ Ọlọrun ni pe (kú).

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.