Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Buhari gba isẹ́ lọ́wọ́ olùdarí ilé-isẹ́ ọkọ̀ oju omi,Hadiza Bala Usman

Ademọla Adepọju

169

Ààrẹ  Muhammadu Buhari ti ní kí olùdarí ilé-isẹ́ ọkọ̀ oju omi,(Nigerian Ports Authority, NPA)Hadiza Bala Usman,lọ rọ ọ́ kún sílé ná, aarẹ Muhammadu Buhari tún wá fọwọ́sí ohun tí minisita  tó ń mójútó ètò ìrìnnà lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà, Rotimi Amaechi,sọ láti yan ìgbìmọ̀ olùwádìí láti ṣe ìwádìí àwọn olùsàkoso ilé-isẹ́ ọ̀hún.

Bakan naa ni aarẹ Buhari wa yan oludari ẹka to n mojuto eto isiro ati isẹ́ , Mohammed Koko lati maa se oludari ile-isẹ́ naa.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.