Take a fresh look at your lifestyle.

Sweden Tẹ̀síwájú Láti Ṣé Ìrànlọ́wọ́ $680m Fún Ukraine Nínú Ogún

233

Ilé-iṣẹ́ Ààbò ti Sweden sọ pé Orílẹ-èdè rẹ̀ yóò tẹ̀síwájú lórí ìrànlọ́wọ́ ogún sí Ukraine pẹ̀lú bílíọ̀nù méje lè díẹ̀ owó Sweden (7.1 billion crown)($682 million), pẹ̀lú àwọn òun èlò ogún àtí owó fún rírà òun ìjà.

Ìròyìn sọ pé yóò jẹ́ ìgbà kẹẹdogun tí Sweden yóò ṣé ìrànlọ́wọ́ fún Ukraine èyí tó pọ̀jù tí orílẹ-èdè náà yóò ṣé. Pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ èyi, gbogbo owó tí Sweden fún Ukraine láti ọdún 2022 tí Orílẹ̀-èdè Russia tí kọlù wọ́n jẹ́ ọgbọ́n Bílíọ̀nù Crown owó ilẹ́ Sweden.

“A ó tẹ̀síwájú látí ṣé àtìlẹ́yìn fún Ukraine níwọ̀n ìgbà tí ogún bá ṣí ń tẹ̀síwájú,” Mínísítà Ààbò, Pal Jonson sọ fún àpéjọ àwọn oníròyìn kàn.

Comments are closed.

button