Àwọn Ọmọ-ogún Orílẹ̀-èdè Somalia yóò ní ànfààní látí tẹ̀síwájú lẹyìn tí àwọn Ọmọ-ogún Áfíríkà (AU) bá kú rò ní Orílẹ̀-èdè náà ní òpin ọdún tó ń bọ̀ 2024, ní ìdánilójú Ààrẹ Somalia Hassan Sheikh Mohamoud, pẹ̀lú àkíyèsí pé rògbòdìyàn náà tí dáwọ dúró fún ìgbà díẹ̀ bí wọ́n ṣé ń kojú àwọn Al-Shebab.
Wọ́n ṣé ìfilọ́lẹ̀ ní Oṣù Kẹjọ ọdún 2022 ní àárín orílẹ̀-èdè náà, ikọlù tí wọ́n ṣé sí ẹgbẹ́ náà tó ní ń kàn ṣé pẹ̀lú al-Qaeda, èyítí o tí gbógun tí àwọn aláṣẹ Somalia fún ọdún mẹ́rìndínlógún, àwọn ọmọ-ogún náà tí gbìyànjú láti dá wọ́n lọwọ́ kọ́.
Àwọn ọmọ-ogún Somalia, tí ní nkán ṣé pẹ̀lú àwọn aráàlú èyí tó tí ṣé àtìlẹ́yìn fún àwọn ẹgbẹ́ ọmọ-ogún Áfíríkà (Atmis), látí gbá àwọn àgbègbè nlá kán, pàápàá ní àárín gbùngbùn orílẹ̀-èdè náà.
Atmis tó jẹ́ àwọn ọmọ-ogún látí Burundi, Djibouti, Ethiopia, Kenya, àtí Uganda.
Leave a Reply