Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Taiwan: Ẹnìkan Kú, Mẹwàá Sọnù Níbi Ìjàmbá Iná Ilé Iṣẹ́

0 412

 

Ẹnìkan kú, mẹwàá sọnù níbi Ìjàmbá Iná àti ìró gbàmù tó ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ Ẹtì ní ilé iṣẹ́ kan to ń se ohun èèlò gọ́ọ̀fù ní gúsù orilẹ-ede Taiwan, ìjọba sọ èyí.

Ilé ìṣẹ́ panápaná Ilẹ̀ náà sọ pé ìjàmbá náà wáyé níbi ẹ̀rọ amúnáwá ní agbègbè ti ilé ìṣẹ́ pọ̀ sí ní ìlú náà.

Panápaná kan gbẹ̀mí mì, mẹ́ta nínú àwọn ènìyàn mẹwàá di ẹni tí wọ́n ń wá
panápaná kan fi èyí kun.

Ó ti tó bí ọgọ́rùn ún èniyàn tó ti farapa tí wọ́n sì ti gbé wọn lọ sí ilé ìwòsan bi wọn se sọ.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button