Wọ́n tí rọ́ Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bola Ahmed Tinubu, látí parí ilé-ìwé gíga tí University of Agriculture, Bassambri ní Nembe Kingdom, Bayelsa State, tí ìjọba àna fọwọ́sí.
Ìpe náà ló jáde láti inú àlàyé kàn tí Ọba àgbègbè náà, Ọba Amanayabo tí opu-Nembe, Kábíyèsí Ọba Biobelemoye Josiah fọwọ́sí.
Tún kà nípa:Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ekiti Se Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Àgbẹ̀ Pẹ̀lú Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Mílíọ̀nù
Ọba náà tún pé Ààrẹ tó ṣé àbẹ̀wò sí Ilé-ẹ̀kọ́ gíga náà láti gbìyànjú yíyan ọmọ bíbí ìlú náà gẹ́gẹ́ bí Ìgbákejì Alákóso (Vice Chancellor) tí ilé-ẹ̀kọ́ náà.
Ẹ rántí pé Ààrẹ tẹ́lẹ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari, ti fọwọ́ sí ìdásílẹ̀ ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Federal University of Agriculture Bassambri, ní ìpínlẹ̀ Bayelsa, ní Gúúsù-gúúsù Nàìjíríà.
Leave a Reply