Take a fresh look at your lifestyle.

Kòsí aáwọ̀ kankan láàrin àwọn aláṣẹ àti aṣòfin – ilé-iṣẹ́ ààrẹ

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 534

Ilé-iṣẹ́ ààrẹ ti sojú abẹ níkòó lórí àríyànjiyàn tí ó wáyé láàrin Aláṣẹ àti àwọn abala aṣòfin  ìjọba lórí àwọn àtúnṣe inú ìsúná ọdún 2022.

Agbẹnusọ fun Aarẹ, Garba Shehu, ninu ọrọ kan, sọ pe awuyewuye yii ko jẹ nkankan bikoṣe erongba awọn oniwa buruku.

Shehu sọ pe  ariyanjiyan ko le maa waye laarin awọn alajọṣepọ,yoo yanju lalaafia naa ni.

O ni gbogbo awon ti won n gbiyanju lati da wahala silẹ laarin Alaṣẹ ati awon  asofin yoo kuna ninu aṣẹ wọn.

Agbẹnusọ fun aarẹ sọ pe awọn apa ijọba mejeeji mọ  ẹtọ to tọ ofin  wọn ati pe wọn si bọwọ fun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button