Take a fresh look at your lifestyle.

Iró Ìbọn Ń Dún Kíkàn Mọ́jú Ní Olú-ìlú Orílẹ̀-èdè Guinea-Bissau

0 275

Iró ìbọn ń dún kíkàn kíkàn látí òru Ọjọ́bọ̀ tí tí dì òwúrọ̀ ọjọ́ Ẹtì ní Olú-ìlú Orílẹ̀-èdè Guinea-Bissau.

Ìdí tí ìbọn ṣé ń dún kó yé ẹnìkán.

Ìròyìn kan sọ pé ìbọn ni a kọ́kọ́ gbọ́ lẹ́yìn ọ̀gànjọ́ òru ní àdúgbò Antula, ní ẹ̀yìn odi ìlú ńlá náà, níbi tí Olórí ọmọ-ogún kàn ń gbé.

Ọkọ àwọn ọmọ ológun wà ń lọ́ káàkiri ní Òpópó-ọ̀nà ní òwúrọ̀ ọjọ́ Ẹtì bí àwọn olùgbé ṣé ń lọ́ sí ẹnú iṣẹ́ àtí ilé-ìwé.

Á sí tún ùn gbógun ìbọn ṣùgbọ́n ó kéré sí tí òru.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button