Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ògùn Ṣètò Ìṣúná N703.03bn fún ọdún 2024

0 267

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ogun, Dapo Abiodun tí gbé iwè àbàdòfin ètò ìṣúná ìnáwó owó tí ọdún tó ń bọ̀ to je 703.03 bílíọ̀nù Náírà sí ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ìjọba ìpínlẹ̀ náà, nígbàtí wọ́n tí yá bílíọ̀nù 415.66 náírà sọtọ fún àwọn ìnáwó iṣẹ́ nlá, tí bílíọ̀nù 287.37 náírà wà fún ìnáwó lóòrèkóòrè.

Àbàdòfin ètò ìṣúná ìnáwó náà tí wọ́n pé ní “Ètò Ìṣúná tó wà fún ìgbéga àti ìdàgbàsókè ìlú” (Budget of Sustained Growth and Development), tún ní bílíọ̀nù 95.05 náírà gẹ́gẹ́ bí ìyè owó àwọn òṣìṣẹ́, pẹ̀lú bílíọ̀nù N105.88 náírà tí a yáa sọtọ fún àwọn ìnáwó àtí bílíọ̀nù 59.09 náírà fún ìdíyelé gbèsè tí Ìpínlẹ̀ náà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button