Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpínlẹ̀ Enugu Gbé Èsì Ìbò Ìjọba Ìbílẹ̀ Mẹ́tàdínlógún Jáde

0 332

Àjọ elẹ́tò ìdìbò lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà (INEC) ní Ìpínlẹ̀ Enugu ti gbé èsì ìbò Ìjọba Ìbílẹ̀ mẹ́tàdínlógún jáde

Ọ̀gá àgbà tó ń se àkójọpọ̀ èsì ìbò, Ọ̀jọ̀gbọ́n Maduebibisi Iwe, ló kéde rẹ̀ ní ọjọ́ ajé ní gbọ̀ngàn àjọ INEC ní Enugu.

Ọ̀jọ̀gbọ́n náà sọ pé, iye àwọn tó forúkọ sílẹ jẹ : 456,424.
Àwọn ènìyàn tó dìbò jẹ́: 457424
Ìbò ti wọ́n fọwọ́sí lápapọ̀: 482990

 

Bí ìbò se lọ nìyí:

Ẹgbẹ́ Òṣèlú/ Ìbò

PDP- 15,749

NNPP-1,808

APC. 4,772

LP –  428,640

Ìbì tí wọ́n gbà : 457,424

Ìbò tí wọ́n kọ̀: -12,467

Ìbò Lápapọ̀: 468,891

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button