Ilé –isẹ́ MORISON INDUSTRIES PLC àti CONOIL PLC ló jáwé olùborí nínú àtẹ ìdókoòwò
Ademọla Adepọju
Ile-isẹ to n mojuto eto tita-rira idokoowo , ti a mọ si Nigerian Exchange Limited (NGX) ti ni awọn ile-isẹ to n ta-ra epo rọbi lo jawe olubori ninu atẹ idokoowo ti wọn se lọsẹ yii.
Amọsa, awọn ile-isẹ bii , GUARANTY TRUST BANK PLC, JULI PLC ati CWG PLC ni wọn fidi rẹmi ninu eto rira-tita lori atẹ eto idokoowo ti ọse yii.
Leave a Reply