Ilé iṣé Agrolearn to jẹ ilé iṣé to ni ìmọ nípa ètò ọ̀gbìn àti oúnjẹ ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ nípa ìdàgbàsókè ètò ounjẹ pẹ̀lú ààbò tó péye.
Ilé iṣé náà wà láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ọ̀gbìn àti àtúnse nipa ọ̀rọ̀ ìmọ fún ààbò tó péye ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Olùdásílẹ̀ ilé iṣé náà, Tolulope Aina lo sọ èyí di mímọ̀ ni ọjọ́ ẹtì ni ìlú Eko.
O ní isé àwon ni láti mú ìmólè bá ètò ọ̀gbìn àti oúnjẹ
Ìyáàfin Remi George -Ashiru ti onímọ̀ ẹ́rọ̀ Ibilola Kasunmu sójú fún gbósùbà káre fún ilé iṣé náà fún àtúnse tó mú wà sí ònà ẹ̀tọ̀ ọ̀gbìn.
Ó ní àwọn yóò bá ilé iṣé náà dà òwò pọ̀ pẹlu ìrètí wí pé gbogbo yóò mú èrè nla jáde.
Leave a Reply