Take a fresh look at your lifestyle.

Pontiff Yóò Simi Fún Àwọn Ìsìn Àárín Ọ̀sẹ̀ Lẹ̀yìn Iṣẹ́ Abẹ Rẹ̀

0 273

Àwọn Dókítà tí o ń ṣe ìtọ́jú pòópù Francis sọ wí pé ó ń ìyàtò n wà, ṣùgbọ́n ki o sí Simi fún àwọn ètò ìsìn

Wákàtí mẹ́ta ni ó fi ṣiṣẹ́ abẹ fún àtúnse inu rẹ,ni ilé ìwòsan Rome Gemelli ni ọjọ́rú.

Ọ̀rọ̀ láti ẹnu Dọ̀kítà oníṣe abẹ Sergio Alfieri sọ wí pé ẹni ọdún mẹ́rìndínláàdọ́rún náà ko ni ṣe iṣẹ́ ìsìn rẹ lakọkọ yìí láti dènà ìpalára lẹ́yìn iṣé abẹ náà.

Ó ni o ṣeéṣe kí póòpù sí wa ni ilé ìwòsan ní gbogbo ọ̀sẹ̀ yìí.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button