Ilé-ẹjọ́ àtúntò ìdìbò tí Ìpínlẹ̀ Cross River bẹ̀rẹ̀ ìgbẹ́jọ̀ lórí ìdìbò gbogbogboo tó wáyé ní ní Ìpínlẹ̀ náà ní Oṣù Kẹta ọdún yìí ni olúìlú ìpínlẹ̀ Cross River, Calabar.
Ilé-ẹjọ́ náà, tó yẹ́ kó bẹ̀rẹ̀ ìgbẹ́jọ̀ náà látí Ọjọ́ Kẹta Oṣù Karùn-ún Ọdún 2023 ní Calabar, rí ìdìwọ́ látàrí ìdáṣẹ̀sílẹ̀ àwọn òṣìṣẹ́ ìdájọ tí ẹ̀kà ìpínlẹ̀ Cross River (JUSUN).
Bó tí lé wù kó rí, níbí ìfilọ́lẹ̀ ìpàdé náà ní Alága ilé-ẹjọ́ náà, Onídàájọ Olukayode Adeniyi pẹ̀lú Adájọ Eva Okonkwo àti Onidajọ Z.U. Modibbo ṣé ìdánilójú pé àwọn kó ní fí àkókò àtí ìlànà ijẹjọ ràré bótíléwù kóri.
Tún kà nípa: ìbò Adeleke ní ìpínlẹ̀ osun ní màgó mágó nínú – Ilé ẹjọ́ Trìbúnà ló sọ bẹ́ẹ̀
Adájọ Adeniyi tún ṣé ìlérí pé ìgbìmọ̀ náà yóò ṣé òdodo sí gbogbo àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú, Ó sọ pé “Ìlé-ẹjọ́ kìí ṣé ààyè ogún. A yóò ṣé àwọn iṣẹ́ wà bótíyẹ́ dáradára gẹ́gẹ́ bí àgbàrá wà l’aini fí àkókò kánkan rare pẹ̀lú ìdájọ tó múná dóko.”
Leave a Reply