Take a fresh look at your lifestyle.

TotalEnergies U17 AFCON: Burkina Faso Gbómijé Lójú Nigeria Nígbàtí Mali Lú Congo Ní Àlùbámi

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 453

Burkina Faso lú ìkọ Nàìjíríà 2-1 ní pápá iṣere Nelson Mandela ní Algiers ní Ọjọ́bọ̀ látí tèsíwájú nínú ìdíje TotalEnergies U17 Africa Cup of Nations (AFCON), àtí ànfààní látí kópa nínú ìfé Àgbáyé FIFA U-17 World Cup.

Aboubacar Camara ló gbà àmì ayò méjèèjì wọlé fún ìkọ Junior Stallions látí bórí ìkọ Flying Eagles tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nínú ìdíje náà. Èyí jẹ́ òun ìwúrí fún Burkina tó pàdánù sí ọwọ́ ìkọ Nàìjíríà níbí àṣé kágbá ìdíje WAFU Zone pẹ̀lú àmì ayò méjì sí ọkàn (2-1).

Tún kà nípa: AFCON U-17: Gusau gba Golden Eaglets níyànjú láti fi àjùlọ han Morocco

Ẹ̀wẹ̀, Mali Lú Congo ní ayò mẹ́ta sí ọkàn (3-0). Ange Tia, Mamadou Doumbia ati Mohamoud Barry ní àwọn àgbábọ́ọ̀lù mẹ́ta tó gbà ayò wọlé fún Mali látí peregede ní Annaba, sí ìpele àṣé kágbá àtí ní anfààní látí kópa nínú ìfé Àgbáyé FIFA World Cup.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button