Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Bọ̀rọ̀nú Fọwọ́sí Àtúnṣe ibùgbé àwọn Dọ́kítà àti ìgbanisíṣẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ ìlera

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 356

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Bọ̀rọ̀nú, Ọ̀jọ̀gbọ́n Babagana Umara Zulum, ti fọwọ́sí àtúnṣe àwọn ilé tí àwọn ènìyàn kò gbé,tí ó ti   bàjẹ́  fún àwọn dókítà, pẹ̀lú olùdarí àgbà oníṣègùn (CMD), ní Ilé-ìwòsàn Gbogbonìṣe ní Bama.

Zulum ṣabẹwo si ile-iwosan naa ni sgogo mẹwaa alẹ, fun ibojuwo awọn iṣẹ ilera gbogbogboo.

Gomina tun ṣabẹwo sibẹ lọjọ keji, o si paṣẹ fun awọn alaṣẹ  Ijọba Ipinlẹ to yẹ lati rii daju pe atunṣe naa bẹrẹ loni  Ọjọọru,o ṣalaye igbaradi rẹ lati fọwọsi  owo lẹsẹkẹsẹ lẹyin ti wọn ba ṣe igbelẹwọn gbogbo awọn ile naa ati afojusun iye ti o le to.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button