Ìgbákéji agbẹ́núsọ tí Ilé-ìgbìmọ́ Aṣóju ṣofìn tí Naijiria, Benjamin Kalu sọ pé Ìlé-ìgbìmọ́ àṣofìn gbọ́dọ̀ ríi dájú pé gbogbo àwọn ìlànà ofiìn àtí àbádofìn rẹ̀ ṣé déédé ọná abàyọ́ áìní àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Naijiria nípasẹ ìṣákósó tó dará.


Ó sọ ọrọ náà lákòkò tó nbá àwọn ákẹ́gbẹ́ rẹ̀ sọrọ nínú ìpádé ọ̀lọ́jọ́ méji kàn ní Ikot-Ekpene, Ìpínlẹ́ Akwa Ibom, tí wọ́n ṣéto fún àwọn aṣoju títún kẹ́wàá ní orílẹ̀-èdè náà.


Kalu sọ pe o jẹ dandan fun ile igbimọ aṣofin lati mọ awọn iwulo awọn eniyan ati awọn oun to n koju wọn.
Lekan Orenuga
Leave a Reply