Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara AbdulRahman AbdulRazaq ti kí Ààrẹ tuntun fún àjọ (ICSAN) Ìyáàfin Funmi Ekundayo, o ní yíyan ti wọn Yan sípò jẹ àtẹ̀gùn ìgbega fún àwọn Obìnrin.
Gómìnà AbdulRazaq sọ èyí di mímọ̀ ni ilé iṣé ìjọba láti ọwọ́ Akọ̀wé fún Gómìnà, Rafiu Ajakaye ni ọjọ́ Ìsimi.
Ìyáàfin Ekundayo jẹ ọmọ ìlú Èkìtì ni ìjọba ìbílẹ̀ Obbo-Aiyegunle, o sí jẹ Obinrin àkọ́kọ́ tí yóò di Ààrẹ fún àjọ ICSAN.
Leave a Reply