Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ebonyi Yóò Ṣètò Àwọn Ilé-ìwé Ìdàgbàsókè

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 255

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ebonyi Ọ̀gbẹ́ni Francis Ogbonna Nwifuru nínú ìgbìyànjú rẹ̀ látí ríi dájú pé gbogbo ọmọ Ìpínlẹ̀ náà ní iṣẹ́ lọ́wọ́, yálà, pẹ̀lú Ilé-iṣẹ́ kàn tàbí àdáni. Ó ṣàfihàn àwọn ètò láti ṣé ìdásílẹ̀ àwọn ilé-iṣẹ́ ìdàgbàsókè mẹ́ta ní Ìpínlẹ̀ náà.

Kọmisọna Ìpínlẹ̀ fún iṣẹ́ ìdàgbàsókè àti ìdásílẹ̀ iṣẹ́, Ọ̀gbẹ́ni Elijah Oko-Udu, ló sọ eléyìí ní Abakaliki, Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ náà.

Komisona náà sọ pé èyí wà ní ìbámu pẹ̀lú àwọn ìtọ́sọ́nà Gómìnà Nwifuru fún ilaniloye fún àwọn ọmọ Ìpínlẹ̀ Ebonyi ní ilé, lókó.

Kọmisọna náà ṣàlàyé pé àwọn òun èlò iṣẹ́ náà ní wọ́n yóò pèsè fún àwọn olukopa látí ṣé ìwúrí fún àwọn ilé-iṣẹ́ kerejekereje àti alabọde (SMEs).

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button