Ebonyi: NYSC gbóríyìn fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ lóríi bí wọ́n ṣe ṣe nínú ìdìbò tó kọjá
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Ẹgbẹ́ Àgùnbánirọ̀ ní ị̀pínlẹ̀ Èbònyì, gúsù iwọ̀ oòrùn Nàìjíríà ti gbóríyìn fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tó kópa nínú ìdìbò ààrẹ àti ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin, fún ìwà ìfàyàbalẹ̀ àti ìkóra ẹni níjàánu tí wọ́n fi hàn lásìkò ìdìbò.
Adarí NYSC ti ìpínlẹ̀, Ìyáàfin Mercy Bamai ṣe ìgbóríyìn yìí lásìkò ìyanbí ológun àbájáde Ikọ̀ ‘A’, stream ‘II’,ọdún 2022,ní Abákáliki,olú-ìlú.
Adarí NYSC ti ìpínlẹ̀ náà, wá sọ pé wọ́n tún le kópa nínú ìbò gómìnà àti ti ilé ìgbìmọ̀ ìpínlẹ̀.
Leave a Reply