Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ Bọ̀wọ̀ Fún Ìlànà Àti Ìfẹ Orílẹ̀-èdè Yìí Tẹ́ Bá Dì Ààrẹ Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin – Ahmed Lawan

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 504

Ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ògbéni Ahmed Lawan, so pé ṣáájú kí wọ́n tó yán àwọn Olùdarí ile-igbimo Aṣòfin kẹwàá pé, kí wọ́n bọ̀wọ̀ fún ìgbéga orílẹ̀-èdè ẹ̀tọ́ ìlú.

Ó fí kùn ùn pé ìlànà Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin ṣé kókó nínú yíyan àwọn Olùdarí àwọn aṣòfin.

Lawan n bá àwọn òníròyìn sọ̀rọ̀, lẹyìn ìgbà tó ṣé ìpàdé pẹ̀lú Ààrẹ Bola Tinubu ní ilé ìjọba Àpapọ̀, Abuja.

Tún kà nípa:Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣé Ìpàdé Pẹ̀lú Àwọn Aṣáájú Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àpapọ̀ Orílẹ̀-èdè

Lawan sọ pé òún yóò tẹ̀síwájú gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ réré fún ìṣàkóso, All Progressive Congress (APC,) látí ríi dájú pé àwọn Olùdarí tó tọ farahàn pẹ̀lú àlàáfíà

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button