Àwọn drones méjì kàn jálúlẹ̀ ní kùtùkùtù ọjọ́ Àìkú ní agbègbè Kaluga tí Russia, Gómìnà tí Ìpínlẹ̀ naa, Vladislav Shapsha, sọ lórí Telegram.
Ọkàn nínú àwọn drone yíi jálúlẹ̀ nítòsí abúlé Strelkovka, nígbàtí òmíràn já sínú igbó ní àgbègbè Medynsky ṣùgbọ́n kòsí ẹnikẹ́ni tó f’àrápá.
Tún kà nípa:Orílẹ̀-èdè Faransé Kìlọ Fún Iran Lórí Fífi Drone Ránṣẹ́ Sí Russia
Àwọn àgbègbè wọnyí ló wà ní tosí Ukraine
Leave a Reply