Ààrẹ Faransé Emmanuel Macron tí kìlọ fún Ààrẹ Iran Ebrahim Raisi nípa ìpàdábọ̀ àwọn ọkọ ìjà ofurufu (Drone) rẹ̀ tó fí ń ránṣẹ́ sí Russia.
Ilé-iṣẹ́ Ààrẹ Faransé náà sọ nínú àlàyé kàn pé Ààrẹ Macron rọ́ Ààrẹ Iran látí dẹkùn àtìlẹ́yìn tó ń fún Russia nínú ogún Ukraine ní kíákíá.
Britain, Faransé, Germany, America àti Ukraine sọ pé ìpèsè àwọn òun ìjà lòdì sí òfin Ìgbìmọ̀ Ààbò Àgbáyé (UN Security Council) 2015 tó fí ayé ṣí ṣé àwọn òun ìjà yìí ní Iran
Leave a Reply