Browsing Category
ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
This is a category for world news
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Pẹ̀lú Orílẹ̀ Èdè Netherlands Fọwọ́sowọ́pọ̀ Lórí Ọ̀gbìn Tòmátò Pẹ̀lú Ìmọ̀ Ẹ̀rọ…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti gúnlè ṣíṣe àmúlò anfààní ìmọ̀ ẹ̀rọ aláìlééfín láti ṣe ogbin Tòmátò lọ́pọ̀ yanturu pẹ̀lú Orílẹ̀ Èdè Netherlands.
Ẹni tíì ṣe Alákòóso àgbà ilé Àjọ Ìdàgbàsókè Òkòwò Iṣẹ́ Àgbẹ̀ ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ (Oyo State Agribusiness…
Albanese Jáwé Olúborí Fún Sáà Kejì Gégébí Alàkóso
Anthony Albanese tí jáwé Olúborí láti dárí Orílẹ̀-èdè Australia fún sáà keji gẹ́gêbí Alàkóso Orílẹ̀-èdè náà.
L'àkókò tí kíkà ibo sí ń tẹ̀síwájú fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọjọ́, àwọn àsọtẹlẹ fihàn pé ẹgbẹ́ Labour tí Albanese wà lórí ọnà látí…
Ecowas Pé Fún Ọwọ̀ Lórí Ìjọba Venezuela
Àwùjọ Ètò-ọrọ-àjé tí Àwọn Orílẹ̀-èdè Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà (ECOWAS) sọ pé àwọn wó idagbasoke túntún tí ń lọ́ ní Orílẹ̀-èdè Venezuela pẹ̀lú àníyàn nlá.
Gbólóhùn kan lati ọdọ Igbimọ ECOWAS sọ pe òun mọ́ pé ẹtọ wà láti kojú awọn òun ti kò…
Póòpù Leo Kẹrìnlá Kéde Láti Gba Àlàáfíà Láyè
Olórí Kátólíìkì, Póòpù Leo Kẹrìnlá, ti ké sí àwọn olórí l'àgbáyé, àwọn ìjọba àti àwọn aráàlú láti gba òun tó pè ní “àlàáfíà aláìlọ́wọ́ àti tí kò ní òun ìjà” gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà tí ó dájú jùlọ sí ìdúróṣinṣin àlàáfíà àgbáyé àti iyì ènìyàn.
…
APEC Ṣé Ìkìlọ̀ Nípa Àwọn ipá Owó-orí-òwò Ọjọ́ Kẹ́ẹ́dógún Ní Oṣù Kàrún, Ọdún 2025
Ẹgbẹ́ Ìṣọ̀kan Ìṣòwò Asia àti Pacific (APEC) tí ṣé ìkìlọ̀ ní Ọjọ́bọ̀ pé àwọn ọjà òkèèrè ní àgbègbè náà kì yóò dàgbà ní ọdún yìí láàrín ìbẹrẹ tí àwọn Owó-orí-òwò tí America.
Àwọn aṣojú ìṣòwò America àti China náà pàdé ní ẹgbẹ kàn níbí…
Orílè-èdè Amẹ́ríkà Pẹ̀lú China Ṣetán Ìpàdé Àpapọ̀ Ní Geneva
Ọ̀gbẹ́ni Scott Bessent àti Jamieson Greer ti orílẹ̀-èdè Amerika yóò pàdé pọ̀ pẹ̀lú He Lifeng ti ilẹ̀ China ní orílẹ̀-èdè Switzerland ní òpin ọ̀sẹ̀ yìí láti sèpàdé pọ̀ lórí ọnà àti fòpin sì ìjà òwó tó n tàbùkù bá ọrọ̀ ajé àgbáyé.…
Ètò Ìfilọ́lẹ̀ Láti Jẹ́ Olórí Kátólìkì Túntún Bẹ̀rẹ̀
Ayé n dúró dè àbájáde ìfilọ́lẹ̀ Olórí Kátólìkì Túntún, tó bẹ̀rẹ ní ọjọ́ kéje Oṣù Kàrún ọdún 2025, bí àwọn kadinali ṣé pejọ ní 'Vatican' láti yán olórí tí Kátólìkì.
Ikú Pope Francis ní ọjọ́ kọkanlelogun, Oṣù Kẹ́rin, ọdún 2025, ní ẹni…
Akọrin Ọmọ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà Kan Kú Sínú Ìjàmbá Iná Inú-ilé
Jill Sobule, gbajúmọ̀ akọrin, olùkọrin-sílẹ̀ Ọmọ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ti wọ́n mọ̀ nípa àkọlé orin rẹ̀ - "LGBTQ+ hit “I Kissed a Girl,” ti ku sínú Ìjàmbá iná inú-ilé ní Woodbury, Minnesota.
Akéde orin ló fi ìròyìn ikú rẹ̀ léde…
Owó Orí Ọjà Amẹ́ríkà Dẹ́rùba Ọrọ̀ Ajé Ilẹ̀ Adúláwọ̀ -Akọ́sẹ́mọsẹ́ Ọmọ Orílẹ̀-èdè Màláwì
Owó orí ọjà Amẹ́ríkà lórí ọrọ̀ ajé ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀ sàkóbá bá ọrọ̀ ajé wọn, orílẹ̀-èdè Màláwì jẹ́ ọ̀kan, akọ́sẹ́mọ́sẹ́ nípa ọ̀rọ̀ òṣèlú-Maclan Kanyang’wa sọ èyí.
Ó sọ pé, oye owó tí wọ́n ń ta nǹkan ní…
Nàìjíríà Kẹ́dùn Pẹ̀lú Iran Látàrí Ìjàmbá Ìbúgbàmù
Ìjọba àpapọ̀ orílè-èdè yìí ti kẹ́dùn pẹlu orílè-èdè Iran látàrí ìjàmbá Ìbúgbàmù tó pa méjìdínlọ́gbọ̀n ènìyàn tó sì jẹ kí ènìyàn tó le lẹ́gbẹ̀rin farapa .
Mínísita ilẹ̀ òkèèrè, Ambasedọ̀ Yusuf Tuggar, ló fi ìkíni ìjọba yìí…