Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

Ó GBÓNÁ FẸLI-FẸLI

This is a category for LATEST NEWS

Nàìjíríà ṣàfilọ́lẹ̀ ìṣàyẹ̀wò ààrùn jẹjerẹ ọ̀fẹ́ jákèjádò orílẹ̀-èdè

Ìjọba Nàìjíríà ti ṣàfilọ́lẹ̀ ètò ìṣàyẹ̀wò ààrùn jẹjerẹ ọ̀fẹ́ jákèjádò orílẹ̀-èdè,tí yọ́ò ṣètọ́jú ẹgbẹ̀rún mẹ́fà ènìyàn jákèjádò ẹkùn mẹ́fà orílẹ̀-èdè. Ètò yìí wà lára àtúnṣe ìgbìyànjú…

Nàìjíríà–Türkiye tẹ̀síwájú lórí igbiyanju fún ọ̀rọ̀ ìtọ́jú pẹ̀lú iwe àdéhùn

Naijiria ti buwọ́lu ìwé àdéhùn (MoU), lórí ìṣọ̀kan àti ìwà lálàáfíà àwùjọ,  tí èyí sì jẹ́ ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ pàtàkì ní ṣíṣe ìfilọ́lẹ̀ àti ìgbòòrò ẹ̀ka ìtọ́jú orílẹ̀-èdè. MoU naa, iwe adehun ẹlẹẹkẹsan…
button