Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GÌN ÀTI ÀYÍKÁ

Di Dènà Omí Yalé: Ìgbìmọ̀ Ìjọba Ti Ìpínlẹ̀ Gombe Buwọ́lù Mílíọ̀nù Mèjídínlógójì Ó lè Mẹ́sàán Náírà…

Àwọn ìgbìmọ̀ ìjọba ìpínlẹ̀ Gombe(SEC) ti buwọ́lù Mílíọ̀nù Mèjídínlógójì ó le Mẹ́sàán Náírà èyí tí o jẹ́ owó ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn àti agbègbè tí omí yalé ṣẹlẹ̀ sí. Kọmísọ́nà fún ètò ìṣúná ni Ìpínlẹ̀ Gombe Malam Mohammed Magaji lo sọ…

Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ Nípa Ètò Ọ̀gbìn Gba Àwọn Àgbẹ̀ Níyànjú Láti Gbin Irúgbìn Tí Ó Dára…

Àjọ kan láti ẹka Ìjọba àpapọ tí ó ń rí sí ètò ọ̀gbìn ti gba àwọn àgbẹ̀ níyànjú  lati gbin irúgbìn tí ó dára èyí tí yóò jẹ́ ọ̀nà àbáyo sí ìsòro àyípadà ojú ọjọ́   Adelé alága àjọ náà, ọ̀mọ̀wé…

Mímú Ìgbòòrò Bá Ètò Ọrọ̀ Ajé Se Pàtàkì Fún Ìdàgbàsókè Orílẹ̀-èdè- Dapọ Abiọdun

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ogun, Ọmọba Dapọ Abiọdun ti pè fún mímú ìgbòòrò bá ètò ọrọ̀ ajé èyí tí yóò se àmójútó Ètò Ọ̀gbìn, Ìmọ̀ Ẹ̀rọ, Ìdàgbàsókè ohun Àlùmọ́ọ́nì àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ   Ó sàlàyé pé…

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọyọ Ti Se Àgbékalẹ̀ Ètò Èyáwó Láti Se Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Àgbẹ̀

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọyọ ti bẹ̀rẹ̀ pínpín owó tí ó tó bílíọ̀nù kan náírà èyí tí yóò jẹ́ owó ìrànlọ́wọ́ fún àwọn àgbẹ̀ ní àwọn ẹkùn méjèèje tí ó wà ní ìpínlẹ̀ náà   Kọmísọ́nà ètò ọ̀gbìn àti…

Ìjọba Àpapọ̀ Pín Ajílẹ̀ Fún Àwọn Àgbẹ̀ Ọ̀gbìn Àlìkáámọ̀ Ní Ìpínlẹ̀ Bauchi

Ìjọba Àpapọ̀ ti pín ajílẹ̀ àti ohun èlò ọ̀gbìn ẹgbẹ̀rún mẹ́ta fún àwọn àgbẹ̀ ọ̀gbìn àlìkáámọ̀ lójúnà àti mú ìgbòòrò bá ètò ọ̀gbìn ní ìpínlẹ Bauchi Ìjọba pín àwọn ohun èlò náà léỳíi tí…
button