Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GBÌN ÀTI ÀYÍKÁ

Ìrọ̀rùn Dé, Ọ̀wọ́ngógó Oúnjẹ Yóò Dẹ̀rọ̀: Àwọn Alẹ́nulọ́rọ̀ Fọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lú Ìjọba…

Lójúnà àti mú kí oúnjẹ pọ̀ yanturu ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àwọn ilé iṣẹ́ kan ti dìde ìrànlọ́wọ́ fún ìjọba àpapọ̀ láti jẹ́ kí ìlérí náà wá sí ìmúsẹ nígbà tí wọ́n jẹ́jẹ̀ẹ́ láti se ìrànlọ́wọ́ fún àwọn…

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kebbi San Owó Fún Àwọn Ti Yòó Ṣe Àtúnṣe Àwọn Pópónà Ìgbèríko.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kebbi ti san Mílíọ̀nù Mẹta ole ni àádọta Náírà fún àwọn òṣìṣẹ́ (RAAMP) ti yóò ṣe àwọn pópónà ìgbèríko. Alhaji Shehu Mu'azu tó jẹ Kọmísọ́nà fún ètò ògbìn àti iṣé ìgbèríko lo sọ èyí di mímọ ní ọjọ́ ajé ni kebbi nígbàtí o n…

Ilé -Iṣẹ́ Tí Ó Wà Ní Títìpa Látàrí Bíba Afẹ́fẹ́ Jẹ́ Ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Ti Bẹ̀rẹ̀ Iṣẹ́…

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti sí ilé isẹ́ tí ó ń lo táyà gẹ́gẹ́ bí ohun èlò ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, èyí tí ó ti wà ní títìpa tẹ́lẹ̀rí látàrí bíba afẹ́fẹ́ jẹ́ àti kíkó ìnira bá àwùjọ   Kọmísọ́nà fún…

Ìjọba Àpapọ̀ Àti Ìpínlẹ Kebbi Ti Parí Ètò Láti Mú Ìgbòòrò Bá Ètò Ọ̀gbìn Èyí Tí…

Ìjọba àpapọ̀ àti Ìpínlẹ̀ Kebbi ti gbé ìgbésẹ̀ akin láti mú ìgbòòrò bá ètò ọ̀gbìn èyí tí yóò mú àdíkù bà ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ, tí oúnjẹ yóò sì wà lọ́pọ̀ yanturu   Mínísítà Fún Ètò Ọ̀gbìn àti…

Ìsẹ̀lẹ̀ Idagiri Ẹgbẹ̀rún Kan-lé-lẹ́ẹ̀dẹ́ẹ́gbẹ̀ta Ní Ó Wáyé Ní Ìpínlẹ̀ Eko Nínú Ọdún…

Àjọ tí ó ń mójútó ìsẹ̀lẹ̀ pàjáwìrì ní ìpínlẹ̀ Eko, (LASEMA) ti sọ pé, ó tó ìsẹ̀lẹ̀ ẹgbẹ̀rún kan lé lẹ́ẹ̀dẹ́ẹ́gbẹ̀ta tí ó wáyé láàrin ọjọ́ kíní osù kíní ọdún 2023 sí ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n osù kejìlá…
button