Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÁNILÁRAYÁ
This is a category for entertainment news
Gbajúmọ̀ Òsèrébìrin Kéde Ìpadàbọ̀ Sí Agbo Òṣèlú
Gbajúmọ̀ òsèrébìrin àti olùṣe fíìmù, Funke Akindele ti kéde èròngbà rẹ láti padà sí agbo òṣèlú látàrí ìfẹ́ tó ní láti sìn ìlú.
Akindele tó jẹ́ igbákejì Olùdíje sí ipò Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP nínú ìbò gbogbogbòò ọdún 2023…
Davido Gba Àmì Ẹ̀yẹ Headies award Ẹlẹ́ẹkẹtàdínlógún Akọrin Òrí Ayélujára Tó Dára Jùlọ
Gbajúmọ̀ Ìràwọ akọrin tàkasùfé ọmọ orílẹ̀-èdè yìí, David Adeleke, tó ti gbá ọpọ àmì ẹ̀yẹ ti gbogbo ènìyàn mọ̀ sì Davido ti gba àmì ẹ̀yẹ Headies award Ẹlẹẹkẹtadinlogun akọrin orí Ayelujara to dára jùlọ ti ọdún yìí.
Àwo rẹ bii “Ogechi…
Falz Ṣetán Láti Gbé Àwo Orin Tuntun Elẹ́ẹ̀kẹfà Jáde
Akọrin tàkasùfé ọmọ Nàìjíríà, Folarin Falana ti ìnangi rẹ̀ ń jẹ́ Falz ti ṣetan láti gbé àwo orin rẹ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹfà jáde tó pè ní - “The Feast”ni Ọgbọnjọ́ oṣù karùn ún, ọdún 2025.
Nígbà ti o n sọ iroyin ayọ̀ náà fún àwọn…
Sinimọ Àwòrẹ̀rín Àti Akọ́nilọ́gbọ́n Kan Yóò Jáde Láìpẹ́
Sinimọ́ kan ti ó pe àkọ́lé rẹ̀ ni "Red Alert" ti Austin Faani ti lu jade ni Dallas, Texas yóò sì jáde laipẹ. Eré náà yóò jáde síta ní sinima orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ki ọdún 2025 tó kógbá sílé.
Fíìmù náà ní ọgbẹni Kizzy…
Agb́abọ́ọ́lù ọmọ orílẹ̀-èdè Gabon, Aaron Boupendza di olóògbé nínú ìṣẹ̀lẹ̀ aburú kan
Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ́lù Gabon (FEGAFOOT), ti fìdí ikú ọmọ agbábọ́ọ́lù fún orílẹ̀-èdè, Aaron Boupendza múlẹ̀ nínú àlàyé kan tí ó fi síta ní Ọjọ́ọ́rú.
Gẹgẹ bi alaye naa ṣe sọ, agbabọọlu ti o jẹ ọmọ ọdun mejidin-lọgbọn, ti…
Ògbóntàrigì Agbábọ́ọ̀lu Sísọ Lójú Ilé Iṣẹ́ Fíìmù Tuntun
Pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Olùdarí ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì, Matthew Vaughn,Cristiano Ronaldo, ògbóntàrigì agbabọ́ọ̀lù ti kánlu agbami òwò ilé iṣẹ fíìmù, ó si ti sí ilé iṣẹ́ Fíìmù àdáni tó pè ní- UR•MARV.
Àjọṣepọ̀ yìí ti bí ṣíṣe àti níná owó lórí fíìmù…
Mínísítà Àṣà Kí Àlàáfín Tuntun Ti Ìlú Ọ̀yọ́ Kú Oríire
Mínísita orílè-èdè yìí fún àṣà, iṣẹ, Ìrìn-àjò òun igbafe àti ọgbọ́n àtinúdá ọrọ̀ ajé, Hannatu Musawa ti kí Àlàáfín tuntun ti Ìlú Ọ̀yọ́, Ọba Abimbola Akeem Owoade, kú oríire, ti ìgorí ìtẹ́ baba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Aláàfin…
Akọrin Ẹ̀mí Steve Crown Kéde Aya Afẹ́sọ́nà Àti Ọjọ́ Ìgbéyàwó Rẹ̀
Gbajúmọ̀ akọrin ẹ̀mí Nàìjíríà, Steve Crown ti kéde ìròyìn ayọ̀ fáráyé gbõ pé òun ti ri ìyàwó, Ruth Thomas.
Àwọn méjèèjì ti wọn ti jọ ń ṣe ọ̀rẹ́ tẹ́lẹ̀ fún ìgbà díẹ kan ti wá kéde ọjó kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin , ọdún…
Àjọ AGN Gbósùbà Fún Ìpínlẹ̀ Plateau Fun Ìtèsíwájú Ilé Iṣẹ Sinimọ́
Àjọ Actors Guild of Nigeria (AGN), ti gbosuba ràbàndẹ̀ fún ijọba Plateau fun akitiyan rẹ ninu ìtesiwaju Ilé Iṣẹ Sinimọ.
Akọ̀wé apapọ àjọ náà, ọgbẹni Abubakar Yakubu, sọ pé akitiyan ìjọba Plateau kò ṣe fi ọwọ́ rọ sẹ́yìn nínú ìdàgbàsókè Ilé…
Oníṣẹ́ Ọnà Ké Gbàjarì Pé Isẹ́ Ọnà Àti Àṣà Wa Kò Gbọdọ̀ Parun
Oníṣẹ́ ọnà kan ní orílẹ̀-èdè yìí, Isah Lawan, ti ke gbajari sì àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè yìí pé isé ọnà àti àṣà wa ti fẹ máa lọ sì oko ìparun.
Ọgbẹni Lawani ti o ti wá nidi isẹ́ ọnà láti bi ogójì ọdún sẹyìn, ẹni ti o n sisẹ́ ní Eko Hotel and…