Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Aláṣẹ Orílẹ̀-èdè Tunisian Bẹ̀rẹ̀ Ìwádìí Nípa Ìṣẹ̀lẹ̀ Ìbọn To wáyé Ni Ilé Ìjọsìn.

0 327

Àwọn aláṣẹ orílẹ́-èdè Tunisian tí bẹ̀rẹ̀ sí ní se ìwádìí lórí bí àwọn agbebọn ṣe pa ènìyàn méjì àti mẹta lára àwọn òṣìṣẹ́ aláàbò.

Ìdí tí agbébọn se fe pa àwọn ènìyàn ní ko ti ye ọpọ èèyàn, ṣùgbọ́n ọkan lára wọn náà jáde láyé ki o to di wí pé o ile to wa Djerba.

Ilé ìjọsìn Ghriba je ọ̀kan lára ilẹ́ ìjọsìn ti o ti wa lati Ayebáyé,ti àwọn ènìyàn tó bá lọ sí ilé mimọ sì ma n ṣe ìbẹ̀wọ̀ sí

Àwọn tí o ti jade láyé látàrí ìṣẹ̀lẹ̀ je márùn-ún ni ọjọ́rú. Àwọn òṣìṣẹ́ aláàbò mẹ́rin láti Orílẹ̀-èdè Tunisian ni o wa ninu bákú-bálà ni ile ìwòsàn báyìí.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button