Bi o ti lẹ jẹ pe o ṣe iṣẹ ti o yanilẹnu ni Serie A, Oludari Alaṣẹ Bayern Munich, Oliver Kahn sọ pe yoo jẹ ewu ńla fun awọn Bavarians lati tọwọ bọwe lori rira ọmọ orílẹ̀-èdè Nàíjíríà Victor Osimhen pẹlu àádọ́ta mílíọ̀nù Euro.
Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàíjíríà ti ni aṣeyori akoko ti o dara julọ lati igba rẹ wa ati pe o mu Partenopei si Scudetto wọ iwe itan akọkọ wọn lẹhin ọdun mẹtalelọgbọn lati di ọmọ orílẹ̀-èdè Nàíjíríà akọkọ lati gba akọle Serie A.
Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàíjíríà lo mi àwọ̀n ni idaji keji, bi Napoli ṣe pada wa lati fi iya jẹ Udinese niyẹn pẹlu ami ayo meji si ẹyọkan
Leave a Reply