Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Tó Jẹ́ Ọmọ wẹ́wẹ́ Farapa Lẹ́yìn Tí Afárá Wó Lulè Ní Orílẹ̀-èdè Finland.

0 228

Àwọn ènìyàn tó tó mẹrindilogun, ti ọ̀pọ̀ nínú wọn jẹ ọmọ kẹkẹ ni o farapa ni Ọjọ́bọ̀ nigba ti Afárá Wò Lulè ni Espoo.

Ìròyìn ní kò sí ẹni tó pàdánù èmi rẹ. Àwọn ọmọ ti ọjọ́ orí won ko ju mẹrinla sí mẹẹdogun lọ ní o ṣẹlẹ̀ sí, nígbà tí wọn lọ si irin ajo pẹ̀lú olukọ wọn.

Ìjàmbá náà fi awon ọmọdé to tó merindin lógbón sínú ìrora.

Àwọn Ọlópàá ní Afárá náà at’isẹ nlọ lọ́wọ́ lórí rẹ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button