Ààrẹ Muhammadu Buhari ti yan ọ̀gagun Garba Umar Ológun to ti feyìntì gẹ́gẹ́ bí olùdámọ̀ràn pàtàkì lórí ètò ààbò nípa àwọn olópàá ni ọfisi mínísítà fún àwọn ọlópàá.
Shehu sọ wí ni yiyan ti Ààrẹ o jẹ awokọṣe sí bí wọn ṣe dá Afẹyinti Kamal Subair dúró wí pé kò sí tèsíwájú lẹnu Iṣẹ́ lọ́dun 2018.
Iṣé AIG Umar dúró gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá ọlọ́pàá ni oṣù kọọkọọla ọdún 2024, ti iṣé rẹ gẹ̀gẹ̀ bi olùdámọ̀ràn yóò bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kerindinlogun oṣù karún-ún ọdún yìí
Leave a Reply