Ikú Gómìnà Fa Awuye-wuye, Rúkè-rúdò Ní Orílẹ̀-èdè Congo
Àjọ Ọmọ Ogun ti Orílẹ̀-èdè DR Congo ti ń gbìyànjú láti dáàbò bo ará ìlú nígbà tí àwọn ọmọ ogun ọlọ̀tẹ̀ fìdí múlẹ̀ ní ìlú Goma, ní Ọjọ́ Ẹtì, èyí tí ó dá ìfòyà, wàhálà sílẹ̀ ní àgbègbè náà
…