Àwọn Olùfi Ẹ̀hónú Hàn padà sí Ojú pópó ní Orílẹ̀ Èdè Sudan
Ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Sudan ti ya sí ojú pópó ní olú ìlú orílẹ̀ èdè náà, Khartoum láti pèpè fún pípadà sí ètò ìjọba tiwa-n-tiwa, lẹ́yìn tí àwọn ológun ti dìtẹ̀ gba ìjọba ní ọdún tí ó kọjá.…