Ẹka Ìjọba àpapọ̀ tí ó ń rí sí ètò ìlera ti fi rinlẹ̀ pé , bílíọ̀nù méwàa ́tí ìjoba pèsè láti fi se ìgúnpá fún ìpèsè òògùn ìdènà àrùn covid-19, léyìí tí ó jẹ́ ti abẹ́lé sì wà ní sẹpẹ́
Mínísítà ètò ìlera, Dókítà Osagie Ohanire fi àrídájú ọ̀rọ̀ náà léde nígbà tí ó ń se àfihàn ibití a bá isé dé ọlọ́sẹ̀ ọ̀sẹ̀ irú rẹ̀ nípa àrùn covid-19. Ó sọ wípé ìjọba ilẹ̀ Nàìjíríà pẹ̀lú akẹgbẹ́ rẹ̀ ní àgbáyé ń gbìnyànjú láti gbógun ti àwọn àrùn tí ó ń dààmú ọmọ nìyàn.
Ó se àfikún pé, pípèsè òògùn ìdènà àrùn tí ó jẹ́ tiwa-n-tiwa se pàtàkì sí ìjọba Muhammadu Buhari, léyìí tí ó sì ń wá gbogbo ọ̀nà láti jẹ́ kí nǹkan náà wá sí ìmús
Leave a Reply