Take a fresh look at your lifestyle.

Kíkó Oúnjẹ Jáde Lọ́nà Àlùmọ̀kọ́rọ́yí Ti Di Èèwọ̀ Ní Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà

Ìjọba àpapọ̀ ti ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn tí ọ̀rọ̀ kàn láti pinwọ́ kíkó oúnjẹ jáde lọ́nà àìtọ́ lọ sí orílẹ̀ èdè míràn. Mínísítà ètò ọ̀gbìn àti ìdàgbàsókè ìgbèríko, ọ̀mọ̀wé Mohammed Abubakar fi…

Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà Se Àmúlò Àbá Àjọ Ilẹ̀ Adúláwọ̀ Lórí Ohun Àtinúdá

Mínísítà tí ó wà fún ìmọ̀-ìjìlẹ̀, ìmọ̀ ẹ̀rọ, àti ohun àtinúdá, ọ̀gbéni Adeleke Mamora sọ wípé, orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ni àkọ́kọ́ ní ibùwọ òòrùn Áfíríkà tí ó se àmúlò àwọn àbá tí àjọ ilẹ̀…

Àjọ Elétò Ìdìbò Pàrọwà Sí Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Fún Ìdáàbòbo Òfin Ìdìbò

Àjọ elétò ìdìbò ilẹ̀ wa (INEC) ti ra ọwọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ẹ̀sọ́ aláàbò fún ààbò tí ó gbépọn àti fún ìgbáradì láti kojú àwọn ìpèníjà tí ó le è kó ìfàsẹ́yìn bá ètò ìdìbò, bíi ríra ìbò, ọ̀rọ̀ òdì nínú…
button