Àjọ Ọmọ Ogun Sọ Ìmọ̀ Àwọn Agbésùmọ̀mí Di Òtúbáńtẹ́ Ní Òpópónà Kaduna
Àjọ Ọmọ Ogun ti ìpín alákọ̀kọ́ọ́ ní Ìlú Kaduna ti se àwọn agbésùmọ̀mí báṣu-bàṣu, tí ọgbọ̀n ènìyàn sì gba òmìnira kúrò lọ́wọ́ àwọn esinsin-ò-kọkú náà. Ikọ̀ Ọmọ Ogun gba Alùpùpù méjì lọ́wọ́ọ wọn, Ó sì sọ…