Take a fresh look at your lifestyle.

Ènìyàn Mẹ́ẹ̀dọ́ọ́gbọ̀n Pàdánù Ẹ̀mí Níbi ị̀kọlù Àwọn Alákatakítí ẹ̀sìn lórílẹ̀ Èdè…

Kò dín ní ènìyàn mẹ́ẹ̀dọ́ọ́gbọ̀n tí wọ́n sòfò ẹ̀mí níbi àkọlù tí àwọn alákatakítí ẹ̀sìn se sí apá Àréwá Burkina Faso ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, gẹ́gẹ́ bíi ìfiléde tí Gómìnà Sahel se.   Ní ọjọ́ Àìkú…

Orílẹ̀ Èdè Tunisia Se Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Tí Ó Fara Káásá Níbi Ilẹ̀ Rírì Ní Turkey…

Orílẹ̀ èdè Tunisia ti darapọ̀ mọ́ ojúgbàa rẹ̀ nípa síṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn tí ó fi ara káásá nínú ìsẹ̀lẹ̀ ilẹ̀ rírì ní orílẹ̀ èdè Turkey àti syria.   Ààrẹ kais Saied fi àwọn ohun atunilára ráńsẹ́ ní…

Ilé Ẹjọ́ Gíga Àpapọ̀ Ti Dá Ilé Ìfowópamọ́ Àpapọ̀ Lọ́wọ́kọ́ Lóríi Gbèdéke Owó Náírà.

Ilé Ẹjọ́ àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà fi ìdájọ́ léde ní Ọjọ́rú (Wednesday) tí ó sí pásẹ fún ilé ìfowópamọ́ àpapọ̀  láti gbésẹ̀ kúrò lóríi gbèdéke kíkó owó Náírà tí ó ti wà tẹ́lẹ̀ rí kúrò nílẹ̀…

Àrọwà Wá Fún Àwọn Olùdíje Sí Ipò Òsèlú Láti Ṣe Ètò Ẹ̀kọ́ Tí Ó Yanjú

Àwọn alámòjútóó ètò ẹ̀kọ́ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti ké sí àwọn olùdíje sípò òsèlú ní ìpínlẹ̀ náà láti fi ọwọ́ bàbàrà mú ètò ẹ̀kọ́ ní ìgbà tí wọ́n bá dé orí ipò.   Àrọwà náà wáyé níbi ìpàdé…

Orílẹ̀ Èdè France Se Ìrànlọ́wọ́ Owó Fún Ìdàgbàsókè Ètò Ọ̀gbìn Ní Nàìjíríà

Ìjọba orílẹ̀ èdè France ti mú ìgbòòrò bá ètò ọ̀gbìn ní orílẹ̀ èdè Nàìjìríà pẹ̀lú pípèsè owó tí ó lé mílíọ̀nù kan owó ilẹ̀ òkèèrè (1.2m Euro). Èyí tí ìrètí wà pé yóò mú àlékún bá ìpèsè…
button