Ìpínlẹ̀ Anambra: Òṣìṣẹ́ Àjọ INEC Ti Gbáradì Tán Fún Ìbò Ààrẹ Àti Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣojú Sòfin
Àwọn òṣìṣẹ́ Àjọ INEC ní wọ́ọ̀dù Kejì ìlú Agulu, Ìpínlẹ̀ Anambra ti gbáradì tán fún Ìbò Ààrẹ àti ti Ilé Ìgbìmọ̀ aṣojú sòfin .
Àwọn tí wọn ti ṣe àyẹ̀wò fún ti wọ́n yege láti dìbò dúró wamuwamu ki ìbò tó bẹ̀rẹ̀.
Ọ̀kan lára…