Anthony Joshua: Mà Fẹ̀yìntì Tí Jermaine Franklin Bá Fẹ̀yìn Mi Balẹ̀
Anthony Joshua sọ pé òun yóò fẹ̀yìntì nínú eré ẹ̀ṣẹ́ jíjà tí afẹ̀sẹ́kù bí òjò ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, Jermaine Franklin bá fi ẹ̀yìn òun gbo ilẹ̀.
Ìdíje ìjàkadì ẹ̀ṣẹ́ wọn yóò wáyé ni ọjọ́ Àbámẹ̀ta, ọjọ kínní oṣù Kẹrin ọdún yí…