Àwọn Adìhámọ́ra Ogun ti pa ènìyàn Mẹ́rìnlá ní itòsí ilu Kaya tó wà ni agbègbè Àríwá. Ológun mẹ́rin sì wà lára àwọn ènìyàn tí wọ́n pa.
Ìròyìn ròó pé ìkọ̀lù náà se pẹki n pẹ̀kí ń pẹ̀kí pẹ̀lú àbẹ̀wò tí adarí ìjọba fìdíhẹ́, Captain Ibrahim Traoré se ní àkókò náà.
Gẹ́gẹ́ bí Ìròyìn se sọ, bí wọ́n ṣe kó àwọn ọmọ ogun orílẹ̀-èdè Faransé kúrò ní orílẹ̀-èdè Burkina Faso àti Mali tí wọ́n sì fi àwọn ajaguntà ti àjọ Russia’s Wagner Group rọ́pò wọn kò so èso rere kankan láti fi ẹ̀yìn ìpáǹle àwọn alákatakítí Jihadi balẹ̀.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply