Take a fresh look at your lifestyle.

Aṣọ Ológun Tí Àwọn Ènìyàn Kan Ńwọ̀ Lòdì Sí Ètò Ààbò – Ológun Ṣe Ìkìlọ̀

Awọn ọmọ ológun orílè-èdè Nàìjíríà tí rọ àwọn olùgbé orílẹ̀-èdè yìí láti yàgò fún wíwọ aṣọ ológun wọn láì se ọmọ ológun Nàìjíríà nitori ṣíṣe èyí a máà tàbùkù bá ìyí àwọn ọmọ Ológun,  a sì máa mú kí ètò ààbò bẹ́ rẹ́lẹ̀. Nígbàtí ó  ń…
button